9 “Kí o ṣe àgbàlá+ àgọ́ ìjọsìn náà. Ní apá gúúsù tó dojú kọ gúúsù, kí àgbàlá náà ní àwọn aṣọ ìdábùú tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀* lílọ́ tó dáa ṣe, èyí tí wọ́n máa ta, kí gígùn ẹ̀gbẹ́ kan jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́.+
9 Ó wá ṣe àgbàlá.+ Ó fi aṣọ ọ̀gbọ̀* lílọ́ tó dáa ṣe àwọn aṣọ ìdábùú tó jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́ tó máa wà ní apá gúúsù àgbàlá náà, níbi tó dojú kọ gúúsù.+