Jẹ́nẹ́sísì 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nígbà tí Ábúrámù pé ẹni ọdún mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún (99), Jèhófà fara han Ábúrámù, ó sì sọ fún un pé: “Èmi ni Ọlọ́run Olódùmarè. Máa bá mi rìn,* kí o sì fi hàn pé o jẹ́ aláìlẹ́bi.* Jẹ́nẹ́sísì 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Màá mú májẹ̀mú mi ṣẹ, tí mo bá ìwọ+ àti ọmọ* rẹ dá jálẹ̀ gbogbo ìran wọn, pé màá jẹ́ Ọlọ́run fún ọ àti fún ọmọ* rẹ. Ẹ́kísódù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà tó yá, Ọlọ́run gbọ́ bí wọ́n ṣe ń kérora,+ Ọlọ́run sì rántí májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù dá.+
17 Nígbà tí Ábúrámù pé ẹni ọdún mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún (99), Jèhófà fara han Ábúrámù, ó sì sọ fún un pé: “Èmi ni Ọlọ́run Olódùmarè. Máa bá mi rìn,* kí o sì fi hàn pé o jẹ́ aláìlẹ́bi.*
7 “Màá mú májẹ̀mú mi ṣẹ, tí mo bá ìwọ+ àti ọmọ* rẹ dá jálẹ̀ gbogbo ìran wọn, pé màá jẹ́ Ọlọ́run fún ọ àti fún ọmọ* rẹ.
24 Nígbà tó yá, Ọlọ́run gbọ́ bí wọ́n ṣe ń kérora,+ Ọlọ́run sì rántí májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù dá.+