Jẹ́nẹ́sísì 46:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn ọmọkùnrin Áṣérì+ ni Ímúnà, Íṣífà, Íṣífì àti Bẹráyà, pẹ̀lú Sírà arábìnrin wọn. Àwọn ọmọ Bẹráyà ni Hébà àti Málíkíélì.+
17 Àwọn ọmọkùnrin Áṣérì+ ni Ímúnà, Íṣífà, Íṣífì àti Bẹráyà, pẹ̀lú Sírà arábìnrin wọn. Àwọn ọmọ Bẹráyà ni Hébà àti Málíkíélì.+