-
Ẹ́kísódù 10:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí tí o ò bá jẹ́ kí àwọn èèyàn mi lọ, màá mú kí eéṣú wọ ilẹ̀ rẹ ní ọ̀la. 5 Wọ́n á bo ilẹ̀ débi pé ilẹ̀ ò ní ṣeé rí. Wọ́n á jẹ ohun tó ṣẹ́ kù fún yín ní àjẹrun, èyí tí òjò yìnyín ṣẹ́ kù, wọ́n á sì jẹ gbogbo igi tó ń hù nínú oko run.+
-