-
Ẹ́kísódù 8:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Jèhófà sì ṣe ohun tí Mósè béèrè. Àwọn àkèré tó wà nínú ilé, nínú àwọn àgbàlá àti nínú oko sì bẹ̀rẹ̀ sí í kú.
-
-
Ẹ́kísódù 8:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nígbà tí Fáráò rí i pé ìtura dé, ó tún mú ọkàn rẹ̀ le,+ kò sì fetí sí wọn bí Jèhófà ṣe sọ.
-