ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 3:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Màá mú kí àwọn èèyàn yìí rí ojú rere àwọn ará Íjíbítì, tí ẹ bá sì ń lọ, ó dájú pé ẹ ò ní lọ lọ́wọ́ òfo.+ 22 Kí obìnrin kọ̀ọ̀kan béèrè àwọn ohun èlò fàdákà àti wúrà pẹ̀lú aṣọ lọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ̀ àti obìnrin tó ń gbé nílé rẹ̀, kí ẹ sì fi wọ àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin yín; ẹ ó sì gba tọwọ́ àwọn ará Íjíbítì.”+

  • Ẹ́kísódù 12:35, 36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ohun tí Mósè sọ fún wọn, wọ́n béèrè àwọn ohun èlò fàdákà àti wúrà pẹ̀lú aṣọ lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì.+ 36 Jèhófà mú kí àwọn èèyàn náà rí ojú rere àwọn ará Íjíbítì, wọ́n fún wọn ní ohun tí wọ́n béèrè, wọ́n sì gba tọwọ́ àwọn ará Íjíbítì.+

  • Sáàmù 105:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Ó mú àwọn èèyàn rẹ̀ jáde tàwọn ti fàdákà àti wúrà;+

      Ìkankan lára àwọn ẹ̀yà rẹ̀ kò sì kọsẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́