Ẹ́kísódù 23:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú.+ Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú ní àkókò rẹ̀ nínú oṣù Ábíbù,*+ bí mo ṣe pa á láṣẹ fún yín, torí ìgbà yẹn lẹ kúrò ní Íjíbítì. Ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ wá síwájú mi lọ́wọ́ òfo.+ Léfítíkù 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù yìí ni Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ fún Jèhófà. Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+
15 Kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú.+ Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú ní àkókò rẹ̀ nínú oṣù Ábíbù,*+ bí mo ṣe pa á láṣẹ fún yín, torí ìgbà yẹn lẹ kúrò ní Íjíbítì. Ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ wá síwájú mi lọ́wọ́ òfo.+
6 “‘Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù yìí ni Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú+ fún Jèhófà. Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+