-
Ẹ́kísódù 4:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Mósè wá pa dà sọ́dọ̀ Jẹ́tírò bàbá ìyàwó rẹ̀,+ ó sì sọ fún un pé: “Jọ̀ọ́, mo fẹ́ pa dà lọ sọ́dọ̀ àwọn arákùnrin mi tó wà ní Íjíbítì kí n lè rí i bóyá wọ́n ṣì wà láàyè.” Jẹ́tírò sọ fún Mósè pé: “Máa lọ ní àlàáfíà.”
-