Léfítíkù 22:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “‘Ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí* ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́.+ Àlejò èyíkéyìí tó wà lọ́dọ̀ àlùfáà tàbí alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́.
10 “‘Ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí* ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́.+ Àlejò èyíkéyìí tó wà lọ́dọ̀ àlùfáà tàbí alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tó jẹ́ mímọ́.