Jẹ́nẹ́sísì 46:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Gbogbo ọmọ Jékọ́bù* tó bá a lọ sí Íjíbítì, yàtọ̀ sí ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ jẹ́ mẹ́rìndínláàádọ́rin (66).+ Diutarónómì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn baba ńlá rẹ àti ìdílé wọn jẹ́ àádọ́rin (70) èèyàn* nígbà tí wọ́n lọ sí Íjíbítì,+ àmọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti mú kí o pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run.+ Ìṣe 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, Jósẹ́fù ránṣẹ́ pe Jékọ́bù bàbá rẹ̀ àti gbogbo mọ̀lẹ́bí rẹ̀ láti ibẹ̀,+ gbogbo wọn* lápapọ̀ jẹ́ márùndínlọ́gọ́rin (75).+
26 Gbogbo ọmọ Jékọ́bù* tó bá a lọ sí Íjíbítì, yàtọ̀ sí ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ jẹ́ mẹ́rìndínláàádọ́rin (66).+
22 Àwọn baba ńlá rẹ àti ìdílé wọn jẹ́ àádọ́rin (70) èèyàn* nígbà tí wọ́n lọ sí Íjíbítì,+ àmọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti mú kí o pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run.+
14 Torí náà, Jósẹ́fù ránṣẹ́ pe Jékọ́bù bàbá rẹ̀ àti gbogbo mọ̀lẹ́bí rẹ̀ láti ibẹ̀,+ gbogbo wọn* lápapọ̀ jẹ́ márùndínlọ́gọ́rin (75).+