Sáàmù 105:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ó na àwọsánmà* bo àwọn èèyàn rẹ̀,+Ó sì pèsè iná láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní òru.+