2 Sámúẹ́lì 22:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Jèhófà wà láàyè! Ìyìn ni fún Àpáta mi!+ Kí a gbé Ọlọ́run tó jẹ́ àpáta ìgbàlà mi ga.+ Àìsáyà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jèhófà, ìwọ ni Ọlọ́run mi. Mo gbé ọ ga, mo yin orúkọ rẹ,Torí o ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+Àwọn ohun tí o pinnu* láti ìgbà àtijọ́,+Nínú òtítọ́,+ nínú ìfọkàntán.
25 Jèhófà, ìwọ ni Ọlọ́run mi. Mo gbé ọ ga, mo yin orúkọ rẹ,Torí o ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+Àwọn ohun tí o pinnu* láti ìgbà àtijọ́,+Nínú òtítọ́,+ nínú ìfọkàntán.