ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 40:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Wo bí àwọn ohun tí o ṣe ti pọ̀ tó,

      Jèhófà Ọlọ́run mi,

      Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ àti èrò rẹ sí wa.+

      Kò sí ẹni tí a lè fi ọ́ wé;+

      Tí mo bá ní kí n máa wí, kí n sì máa sọ nípa wọn,

      Wọ́n pọ̀ ju ohun tí mo lè ròyìn!+

  • Sáàmù 98:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+

      Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+

      Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+

  • Sáàmù 107:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Kí àwọn èèyàn máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà+ nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀

      Àti nítorí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀ lórí àwọn ọmọ èèyàn.+

  • Sáàmù 145:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 145 Màá gbé ọ ga, ìwọ Ọlọ́run mi Ọba,+

      Màá yin orúkọ rẹ títí láé àti láéláé.+

  • Sáàmù 145:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ìran dé ìran yóò máa yin àwọn iṣẹ́ rẹ;

      Wọ́n á máa sọ nípa iṣẹ́ ńlá rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́