ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 33:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ẹ kọ orin tuntun sí i;+

      Ẹ fi ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín dárà, bí ẹ ti ń kígbe ayọ̀.

  • Sáàmù 96:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 96 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà.+

      Ẹ kọrin sí Jèhófà, gbogbo ayé!+

  • Sáàmù 149:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 149 Ẹ yin Jáà!*

      Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà;+

      Ẹ yìn ín nínú ìjọ àwọn adúróṣinṣin.+

  • Àìsáyà 42:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+

      Ẹ yìn ín láti àwọn ìkángun ayé,+

      Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń lọ sínú òkun àti gbogbo ohun tó kún inú rẹ̀,

      Ẹ̀yin erékùṣù àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́