Àìsáyà 33:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+ Ìfihàn 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 wọ́n ní: “A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè, ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ torí o ti gba agbára ńlá rẹ, o sì ti ń jọba.+
22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+
17 wọ́n ní: “A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè, ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ torí o ti gba agbára ńlá rẹ, o sì ti ń jọba.+