Ìfihàn 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Èmi Jòhánù ń kọ̀wé sí àwọn ìjọ méje+ tó wà ní ìpínlẹ̀ Éṣíà: Kí ẹ ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ “Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀”+ àti látọ̀dọ̀ ẹ̀mí méje+ tó wà níwájú ìtẹ́ rẹ̀ Ìfihàn 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo gbọ́ tí áńgẹ́lì tó wà lórí àwọn omi sọ pé: “Ìwọ, Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ Ẹni ìdúróṣinṣin,+ jẹ́ olódodo, torí o ti ṣe àwọn ìdájọ́ yìí,+
4 Èmi Jòhánù ń kọ̀wé sí àwọn ìjọ méje+ tó wà ní ìpínlẹ̀ Éṣíà: Kí ẹ ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ “Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀”+ àti látọ̀dọ̀ ẹ̀mí méje+ tó wà níwájú ìtẹ́ rẹ̀
5 Mo gbọ́ tí áńgẹ́lì tó wà lórí àwọn omi sọ pé: “Ìwọ, Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ Ẹni ìdúróṣinṣin,+ jẹ́ olódodo, torí o ti ṣe àwọn ìdájọ́ yìí,+