Ìfihàn 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 ó sọ pé: “Kọ ohun tí o rí sínú àkájọ ìwé, kí o sì fi ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ méje tó wà ní: Éfésù,+ Símínà,+ Págámù,+ Tíátírà,+ Sádísì,+ Filadéfíà+ àti Laodíkíà.”+
11 ó sọ pé: “Kọ ohun tí o rí sínú àkájọ ìwé, kí o sì fi ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ méje tó wà ní: Éfésù,+ Símínà,+ Págámù,+ Tíátírà,+ Sádísì,+ Filadéfíà+ àti Laodíkíà.”+