Ìfihàn 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Sádísì pé: Àwọn ohun tí ẹni tó ní ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run+ àti ìràwọ̀ méje+ sọ nìyí: ‘Mo mọ àwọn iṣẹ́ rẹ, pé o kàn ní orúkọ pé o wà láàyè* ni, àmọ́ o ti kú.+
3 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Sádísì pé: Àwọn ohun tí ẹni tó ní ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run+ àti ìràwọ̀ méje+ sọ nìyí: ‘Mo mọ àwọn iṣẹ́ rẹ, pé o kàn ní orúkọ pé o wà láàyè* ni, àmọ́ o ti kú.+