Ìfihàn 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Èmi Jòhánù ń kọ̀wé sí àwọn ìjọ méje+ tó wà ní ìpínlẹ̀ Éṣíà: Kí ẹ ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ “Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀”+ àti látọ̀dọ̀ ẹ̀mí méje+ tó wà níwájú ìtẹ́ rẹ̀ Ìfihàn 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mànàmáná+ àti ohùn àti ààrá+ sì ń jáde wá láti ibi ìtẹ́ náà; fìtílà méje tó ní iná ń jó níwájú ìtẹ́ náà, àwọn yìí sì túmọ̀ sí ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run.+
4 Èmi Jòhánù ń kọ̀wé sí àwọn ìjọ méje+ tó wà ní ìpínlẹ̀ Éṣíà: Kí ẹ ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ “Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀”+ àti látọ̀dọ̀ ẹ̀mí méje+ tó wà níwájú ìtẹ́ rẹ̀
5 Mànàmáná+ àti ohùn àti ààrá+ sì ń jáde wá láti ibi ìtẹ́ náà; fìtílà méje tó ní iná ń jó níwájú ìtẹ́ náà, àwọn yìí sì túmọ̀ sí ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run.+