Sáàmù 44:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìwọ Ọlọ́run ni Ọba mi;+Pàṣẹ ìṣẹ́gun pípé fún Jékọ́bù.* Sáàmù 97:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 97 Jèhófà ti di Ọba!+ Kí inú ayé máa dùn.+ Kí ọ̀pọ̀ erékùṣù máa yọ̀.+ Ìfihàn 11:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Áńgẹ́lì keje fun kàkàkí rẹ̀.+ Àwọn ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé: “Ìjọba ayé ti di Ìjọba Olúwa wa+ àti ti Kristi rẹ̀,+ ó sì máa jọba títí láé àti láéláé.”+ Ìfihàn 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 wọ́n ní: “A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè, ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ torí o ti gba agbára ńlá rẹ, o sì ti ń jọba.+
15 Áńgẹ́lì keje fun kàkàkí rẹ̀.+ Àwọn ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé: “Ìjọba ayé ti di Ìjọba Olúwa wa+ àti ti Kristi rẹ̀,+ ó sì máa jọba títí láé àti láéláé.”+
17 wọ́n ní: “A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè, ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ torí o ti gba agbára ńlá rẹ, o sì ti ń jọba.+