Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+ Sefanáyà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà ní àárín rẹ.+ Ó máa gbani là bí Alágbára ńlá. Ó máa yọ̀ gidigidi nítorí rẹ.+ Á dákẹ́ jẹ́ẹ́* nínú ìfẹ́ rẹ̀. Á dunnú nítorí rẹ pẹ̀lú igbe ayọ̀.
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
17 Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà ní àárín rẹ.+ Ó máa gbani là bí Alágbára ńlá. Ó máa yọ̀ gidigidi nítorí rẹ.+ Á dákẹ́ jẹ́ẹ́* nínú ìfẹ́ rẹ̀. Á dunnú nítorí rẹ pẹ̀lú igbe ayọ̀.