Àìsáyà 26:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà títí láé,+Torí pé Àpáta ayérayé ni Jáà* Jèhófà.+