-
Ẹ́kísódù 15:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ọwọ́ ọ̀tún rẹ mà lágbára o, Jèhófà;+
Jèhófà, ọwọ́ ọ̀tún rẹ lè fọ́ ọ̀tá túútúú.
-
-
Àìsáyà 63:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mo wò, àmọ́ kò sẹ́ni tó ṣèrànwọ́;
Ẹnu yà mí pé kò sẹ́ni tó tì mí lẹ́yìn.
-