Àìsáyà 51:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,Ìwọ apá Jèhófà! + Jí, bíi ti àwọn ọjọ́ tó ti pẹ́, bíi ti àwọn ìran tó ti kọjá. Ṣebí ìwọ lo fọ́ Ráhábù*+ sí wẹ́wẹ́,Tí o gún ẹran ńlá inú òkun ní àgúnyọ?+
9 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,Ìwọ apá Jèhófà! + Jí, bíi ti àwọn ọjọ́ tó ti pẹ́, bíi ti àwọn ìran tó ti kọjá. Ṣebí ìwọ lo fọ́ Ráhábù*+ sí wẹ́wẹ́,Tí o gún ẹran ńlá inú òkun ní àgúnyọ?+