ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 87:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Màá ka Ráhábù+ àti Bábílónì mọ́ àwọn tó mọ̀ mí;*

      Filísíà àti Tírè nìyí, pẹ̀lú Kúṣì.

      Àwọn èèyàn á sọ pé: “Ẹni yìí ni a bí níbẹ̀.”

  • Sáàmù 89:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 O ti ṣẹ́gun Ráhábù+ pátápátá bí ẹni tí wọ́n pa.+

      O ti fi apá rẹ tó lágbára tú àwọn ọ̀tá rẹ ká.+

  • Àìsáyà 30:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Torí ìrànlọ́wọ́ Íjíbítì ò wúlò rárá.+

      Torí náà, mo pe ẹni yìí ní: “Ráhábù,+ tó jókòó jẹ́ẹ́.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́