1 Kíróníkà 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà,+ ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+