Sáàmù 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà ni Ọba títí láé àti láéláé.+ Àwọn orílẹ̀-èdè ti ṣègbé kúrò láyé.+