Nọ́ńbà 33:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, wọ́n kúrò ní Píháhírótì, wọ́n sì gba àárín òkun+ kọjá lọ sí aginjù, wọ́n wá rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta ní aginjù+ Étámù,+ wọ́n sì pàgọ́ sí Márà.+
8 Lẹ́yìn náà, wọ́n kúrò ní Píháhírótì, wọ́n sì gba àárín òkun+ kọjá lọ sí aginjù, wọ́n wá rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta ní aginjù+ Étámù,+ wọ́n sì pàgọ́ sí Márà.+