Ẹ́kísódù 15:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Wọ́n dé Márà,*+ àmọ́ wọn ò lè mu omi tó wà ní Márà torí ó korò. Ìdí nìyẹn tó fi pè é ní Márà.