ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 6:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Màá mú yín bí èèyàn mi, màá sì di Ọlọ́run yín.+ Ó dájú pé ẹ ó mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín tó mú yín kúrò lábẹ́ àjàgà àwọn ará Íjíbítì.

  • Nọ́ńbà 16:28, 29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Mósè wá sọ pé: “Èyí á jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé Jèhófà ló rán mi ní gbogbo ohun tí mò ń ṣe yìí, kì í ṣe ohun tó kàn wù mí:* 29 Tó bá jẹ́ pé bí gbogbo èèyàn ṣe ń kú làwọn èèyàn yìí máa kú, tó bá sì jẹ́ irú ìyà ẹ̀ṣẹ̀ tí gbogbo aráyé ń jẹ làwọn náà máa jẹ, a jẹ́ pé Jèhófà kọ́ ló rán mi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́