Ẹ́kísódù 16:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rí i, wọ́n ń bi ara wọn pé, “Kí nìyí?” torí wọn ò mọ ohun tó jẹ́. Mósè sọ fún wọn pé: “Oúnjẹ tí Jèhófà fún yín pé kí ẹ jẹ ni.+ Nọ́ńbà 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ṣẹlẹ̀ pé mánà+ náà dà bí irúgbìn kọriáńdà,+ ó sì rí bíi gọ́ọ̀mù bídẹ́líọ́mù.
15 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rí i, wọ́n ń bi ara wọn pé, “Kí nìyí?” torí wọn ò mọ ohun tó jẹ́. Mósè sọ fún wọn pé: “Oúnjẹ tí Jèhófà fún yín pé kí ẹ jẹ ni.+