Ẹ́kísódù 16:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ilé Ísírẹ́lì pe oúnjẹ náà ní “mánà.”*+ Ó funfun bí irúgbìn kọriáńdà, ó sì dùn bí àkàrà olóyin pẹlẹbẹ.
31 Ilé Ísírẹ́lì pe oúnjẹ náà ní “mánà.”*+ Ó funfun bí irúgbìn kọriáńdà, ó sì dùn bí àkàrà olóyin pẹlẹbẹ.