-
Nọ́ńbà 33:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Bí wọ́n ṣe ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì lẹ́nu ìrìn àjò wọn ni Mósè ń kọ àwọn ibi tí wọ́n ti ń gbéra sílẹ̀, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ. Bí wọ́n ṣe gbéra láti ibì kan sí ibòmíì+ nìyí:
-