-
Diutarónómì 25:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 “Ẹ rántí ohun tí Ámálékì ṣe sí yín lójú ọ̀nà nígbà tí ẹ kúrò ní Íjíbítì,+
-
-
1 Sámúẹ́lì 15:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: ‘Màá pe àwọn ọmọ Ámálékì wá jíhìn nítorí ohun tí wọ́n ṣe sí Ísírẹ́lì bí wọ́n ṣe gbéjà kò ó nígbà tó ń jáde bọ̀ láti Íjíbítì.+
-