-
Nọ́ńbà 24:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Nígbà tó rí Ámálékì, ó ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ lówelówe pé:
-
-
Diutarónómì 25:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 “Ẹ rántí ohun tí Ámálékì ṣe sí yín lójú ọ̀nà nígbà tí ẹ kúrò ní Íjíbítì,+ 18 bó ṣe pàdé yín lójú ọ̀nà nígbà tó ti rẹ̀ yín, tí ẹ ò sì lókun, tó sì gbógun ja gbogbo àwọn tó ń wọ́ rìn lẹ́yìn yín. Kò bẹ̀rù Ọlọ́run.
-