Ẹ́kísódù 24:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mósè gbéra pẹ̀lú Jóṣúà ìránṣẹ́ rẹ̀,+ Mósè sì lọ sórí òkè Ọlọ́run tòótọ́.+ 14 Àmọ́ ó ti sọ fún àwọn àgbààgbà náà pé: “Ẹ dúró dè wá níbí títí a ó fi pa dà wá bá yín.+ Áárónì àti Húrì+ wà pẹ̀lú yín. Tí ẹnikẹ́ni bá ní ẹjọ́, kó lọ bá wọn.”+
13 Mósè gbéra pẹ̀lú Jóṣúà ìránṣẹ́ rẹ̀,+ Mósè sì lọ sórí òkè Ọlọ́run tòótọ́.+ 14 Àmọ́ ó ti sọ fún àwọn àgbààgbà náà pé: “Ẹ dúró dè wá níbí títí a ó fi pa dà wá bá yín.+ Áárónì àti Húrì+ wà pẹ̀lú yín. Tí ẹnikẹ́ni bá ní ẹjọ́, kó lọ bá wọn.”+