Nọ́ńbà 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jóṣúà+ ọmọ Núnì tó jẹ́ ìránṣẹ́ Mósè láti kékeré fèsì pé: “Mósè olúwa mi, pa wọ́n lẹ́nu mọ́!”+