-
Diutarónómì 4:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ẹ wò ó, mo ti kọ́ yín ní àwọn ìlànà àti àwọn ìdájọ́,+ bí Jèhófà Ọlọ́run mi ṣe pa á láṣẹ fún mi gẹ́lẹ́, kí ẹ lè máa pa wọ́n mọ́ ní ilẹ̀ tí ẹ máa gbà.
-
-
Diutarónómì 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mósè wá pe gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì jọ, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ gbọ́ àwọn ìlànà àti àwọn ìdájọ́ tí mò ń kéde fún yín lónìí, kí ẹ mọ̀ wọ́n, kí ẹ sì rí i pé ẹ̀ ń pa wọ́n mọ́.
-