Ẹ́kísódù 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní aginjù Sínì+ láti ibì kan sí ibòmíì bí Jèhófà ṣe pàṣẹ,+ wọ́n sì pàgọ́ sí Réfídímù.+ Àmọ́ àwọn èèyàn náà ò rí omi mu.
17 Gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní aginjù Sínì+ láti ibì kan sí ibòmíì bí Jèhófà ṣe pàṣẹ,+ wọ́n sì pàgọ́ sí Réfídímù.+ Àmọ́ àwọn èèyàn náà ò rí omi mu.