Sáàmù 68:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ayé mì tìtì;+Ọ̀run rọ òjò* nítorí Ọlọ́run;Sínáì yìí mì tìtì nítorí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+