Ẹ́kísódù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+ Àwọn Onídàájọ́ 5:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà, nígbà tí o jáde ní Séírì,+Nígbà tí o kúrò ní ilẹ̀ Édómù,Ayé mì tìtì, omi ọ̀run sì ya,Omi ya bolẹ̀ látojú ọ̀run. 5 Àwọn òkè yọ́* níwájú Jèhófà,+Títí kan Sínáì, níwájú Jèhófà,+ Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+
18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+
4 Jèhófà, nígbà tí o jáde ní Séírì,+Nígbà tí o kúrò ní ilẹ̀ Édómù,Ayé mì tìtì, omi ọ̀run sì ya,Omi ya bolẹ̀ látojú ọ̀run. 5 Àwọn òkè yọ́* níwájú Jèhófà,+Títí kan Sínáì, níwájú Jèhófà,+ Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+