-
1 Àwọn Ọba 1:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Ẹ̀rù Sólómọ́nì ń ba Ádóníjà, torí náà, ó gbéra, ó sì lọ di àwọn ìwo pẹpẹ mú.+
-
-
1 Àwọn Ọba 2:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ìgbà náà ni wọ́n wá sọ fún Ọba Sólómọ́nì pé: “Jóábù ti sá lọ sínú àgọ́ Jèhófà, ó sì wà níbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ.” Torí náà, Sólómọ́nì rán Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà pé: “Lọ pa á!”
-