Diutarónómì 24:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Tí ẹ bá rí ẹnì kan tó jí ọ̀kan* lára àwọn arákùnrin rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì gbé, tó ti fìyà jẹ ẹ́, tó sì ti tà á,+ ṣe ni kí ẹ pa ẹni tó jí èèyàn gbé náà.+ Kí ẹ mú ohun tó burú kúrò láàárín yín.+
7 “Tí ẹ bá rí ẹnì kan tó jí ọ̀kan* lára àwọn arákùnrin rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì gbé, tó ti fìyà jẹ ẹ́, tó sì ti tà á,+ ṣe ni kí ẹ pa ẹni tó jí èèyàn gbé náà.+ Kí ẹ mú ohun tó burú kúrò láàárín yín.+