Ẹ́kísódù 21:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Kí ẹ pa+ ẹnikẹ́ni tó bá jí èèyàn gbé+ tó sì tà á tàbí tí wọ́n ká a mọ́ ọn lọ́wọ́.+