Oníwàásù 10:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kódà nínú èrò rẹ,* má ṣe bú* ọba,+ má sì bú olówó nínú yàrá rẹ; torí pé ẹyẹ kan* lè gbé ọ̀rọ̀* náà tàbí kí ohun tó ní ìyẹ́ tún ọ̀rọ̀ rẹ sọ. Ìṣe 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Pọ́ọ̀lù fèsì pé: “Ẹ̀yin ará, mi ò mọ̀ pé àlùfáà àgbà ni. Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ sọ̀rọ̀ alákòóso àwọn èèyàn rẹ láìdáa.’”+ Júùdù 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láìka èyí sí, àwọn èèyàn yìí ń ro ìròkurò,* wọ́n ń sọ àwọn èèyàn di ẹlẹ́gbin, wọn ò ka àwọn aláṣẹ sí, wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ àwọn ẹni ògo láìdáa.+
20 Kódà nínú èrò rẹ,* má ṣe bú* ọba,+ má sì bú olówó nínú yàrá rẹ; torí pé ẹyẹ kan* lè gbé ọ̀rọ̀* náà tàbí kí ohun tó ní ìyẹ́ tún ọ̀rọ̀ rẹ sọ.
5 Pọ́ọ̀lù fèsì pé: “Ẹ̀yin ará, mi ò mọ̀ pé àlùfáà àgbà ni. Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ sọ̀rọ̀ alákòóso àwọn èèyàn rẹ láìdáa.’”+
8 Láìka èyí sí, àwọn èèyàn yìí ń ro ìròkurò,* wọ́n ń sọ àwọn èèyàn di ẹlẹ́gbin, wọn ò ka àwọn aláṣẹ sí, wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ àwọn ẹni ògo láìdáa.+