-
3 Jòhánù 9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Mo kọ̀wé kan sí ìjọ, àmọ́ Díótíréfè tó fẹ́ fi ara rẹ̀ ṣe olórí láàárín wọn,+ kì í fi ìrẹ̀lẹ̀ gba ohunkóhun tí a bá sọ.+ 10 Torí náà, tí mo bá dé, màá sọ̀rọ̀ nípa ohun tó ń ṣe, bó ṣe ń bà wá jẹ́ káàkiri.*+ Kò fi mọ síbẹ̀ o, kì í tẹ́wọ́ gba àwọn ará,+ kò sì bọ̀wọ̀ fún wọn. Kódà, ó tún ń ṣèdíwọ́ fún àwọn tó fẹ́ gbà wọ́n, ó sì fẹ́ lé wọn kúrò nínú ìjọ.
-