-
Hébérù 9:18-20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Tó bá rí bẹ́ẹ̀, májẹ̀mú ti tẹ́lẹ̀ náà kò lè ṣiṣẹ́* láìsí ẹ̀jẹ̀. 19 Torí lẹ́yìn tí Mósè sọ gbogbo àṣẹ inú Òfin náà fún gbogbo èèyàn, ó mú ẹ̀jẹ̀ àwọn akọ ọmọ màlúù àti ti àwọn ewúrẹ́, pẹ̀lú omi, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti ewéko hísópù, ó sì fi wọ́n ìwé* náà àti gbogbo àwọn èèyàn náà, 20 ó sọ pé: “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Ọlọ́run pa láṣẹ pé kí ẹ pa mọ́.”+
-