-
Ẹ́kísódù 30:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Igi bọn-ọ̀n-ní ni kí o fi ṣe àwọn ọ̀pá náà, kí o sì fi wúrà bò wọ́n.
-
-
1 Kíróníkà 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nígbà náà, àwọn ọmọ Léfì fi àwọn ọ̀pá+ gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ lé èjìká wọn, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Mósè pa látọ̀dọ̀ Jèhófà.
-