-
Ẹ́kísódù 40:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Lẹ́yìn náà, ó gbé tábìlì+ sínú àgọ́ ìpàdé ní apá àríwá àgọ́ ìjọsìn náà ní ìta aṣọ ìdábùú,
-
-
Ẹ́kísódù 40:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Lẹ́yìn náà, ó gbé pẹpẹ wúrà+ sínú àgọ́ ìpàdé níwájú aṣọ ìdábùú,
-