-
Léfítíkù 24:1-3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n gbé ògidì òróró ólífì tí wọ́n fún wá sọ́dọ̀ rẹ láti máa fi tan iná, kí àwọn fìtílà náà lè máa wà ní títàn nígbà gbogbo.+ 3 Lẹ́yìn òde aṣọ ìdábùú Ẹ̀rí nínú àgọ́ ìpàdé, kí Áárónì ṣètò bí àwọn fìtílà náà á ṣe máa wà ní títàn níwájú Jèhófà nígbà gbogbo láti ìrọ̀lẹ́ di òwúrọ̀. Àṣẹ tí gbogbo ìran yín á máa tẹ̀ lé títí láé ni.
-